Òwe 16:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òdiwọ̀n àti òṣùwọ̀n òtítọ́ wá láti ọ̀dọ̀ Olúwa;gbogbo wíwúwo àpò jẹ́ láti ọwọ́ rẹ̀.

Òwe 16

Òwe 16:1-19