Òwe 15:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọkàn olódodo ń wọn ìdáhùn wòṣùgbọ́n ẹnu ènìyàn búburú ń tú ibi jáde.

Òwe 15

Òwe 15:20-30