Òwe 15:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Inú ènìyàn a máa dùn nígbà tí ó bá fèsì tó báa muọ̀rọ̀ tí ó bá sì wá lásìkò tó yẹ dára púpọ̀!

Òwe 15

Òwe 15:14-24