Òwe 15:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Inú ènìyàn aláìlóye a máa dùn sí ìwà òmùgọ̀;ṣùgbọ́n olóye ènìyàn a máa rin ọ̀nà tààrà.

Òwe 15

Òwe 15:13-26