Òwe 15:18-20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

18. Ènìyàn onínú ríru dá ìjà sílẹ̀ṣùgbọ́n onísùúrù paná ìjà.

19. Ẹ̀gún dí ọ̀nà ọ̀lẹṣùgbọ́n pópónà tí ń dán ni ti àwọn dídúró ṣinṣin.

20. Ọlọgbọ́n ọmọ mú inú baba rẹ̀ dùn,ṣùgbọ́n aláìgbọ́n ọmọ kẹ́gàn baba rẹ̀.

Òwe 15