Òwe 15:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọkàn olóye ń wá ìmọ̀ṣùgbọ́n ẹnu aláìgbọ́n ń fẹ́ ìwà òmùgọ̀ bí ẹní jẹun.

Òwe 15

Òwe 15:6-19