Òwe 14:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹni tí ń rìn déédé bẹ̀rù Olúwa,ṣùgbọ́n ẹni tí ọ̀nà rẹ̀ kò tọ́ kẹ́gàn Olúwa.

Òwe 14

Òwe 14:1-9