Òwe 14:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ènìyàn ìkà yóò tẹríba níwájú àwọn ènìyàn rereàti ènìyàn búburú níbi ìlẹ̀kùn àwọn olódodo.

Òwe 14

Òwe 14:13-28