Òwe 13:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òdodo ń ṣamọ̀nà ènìyàn olóòótọ́ inú,ṣùgbọ́n ìwà búburú sí ẹlẹ́ṣẹ̀ nípò.

Òwe 13

Òwe 13:3-15