Òwe 12:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọwọ́ àìṣọ̀lẹ yóò jọbaṣùgbọ́n ọ̀lẹ ṣíṣe a máa yọrí sí sínsìnrú.

Òwe 12

Òwe 12:16-28