Òwe 12:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ̀tàn wà nínú ọkàn àwọn tí ń pète búburúṣùgbọ̀n ayọ̀ wà fún àwọn tí ń mú kí àlàáfíà gbilẹ̀.

Òwe 12

Òwe 12:13-24