Òwe 12:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Aláìgbọ́n ènìyàn fi ìbínú un rẹ̀ hàn lẹ́ṣẹ̀kẹṣẹ̀,ṣùgbọ́n olóye ènìyàn fojú fo ìyànjẹ.

Òwe 12

Òwe 12:6-20