Òwe 11:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹni tí ó ń mú ìdàámú dé bá ìdílé rẹ̀ yóò jogún afẹ́fẹ́ lásánaláìgbọ́n yóò sì máa ṣe ìránṣẹ́ fún Ọlọgbọ́n.

Òwe 11

Òwe 11:25-31