Òwe 11:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ènìyàn a ṣépè lé ènìyàn tí ń kó oúnjẹ pamọ́ṣùgbọ́n ìbùkún a máa wá sórí ẹni tí ó ṣetán láti tà.

Òwe 11

Òwe 11:20-28