Òwe 11:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ènìyàn rere ń ṣe ara rẹ̀ lóoreṣùgbọ́n ènìyàn ìkà ń mú ìyọnu wá sórí ara rẹ̀.

Òwe 11

Òwe 11:15-25