Òwe 11:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa kórìíra òṣùwọ̀n èkéṣùgbọ́n òṣùwọ̀n òtítọ́ jẹ́ inú dídùn un rẹ̀.

Òwe 11

Òwe 11:1-3