Òwe 10:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọwọ́ tí ó lẹ máa ń sọ ènìyàn di talákà,ṣùgbọ́n ọwọ́ tí ó múra síṣẹ́ a máa sọni di ọlọ́rọ̀.

Òwe 10

Òwe 10:3-5