Òwe 10:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ọtí kíkan sí eyín, àti èéfín sí ojúbẹ́ẹ̀ ni ọ̀lẹ sí ẹni tí ó rán an níṣẹ́.

Òwe 10

Òwe 10:21-29