Òwe 10:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú ọ̀rọ̀ púpọ̀ a kò le fẹ́ ẹ̀ṣẹ̀ kùṣùgbọ́n ẹni tí ó pa ẹnu rẹ̀ mọ́ jẹ́ ọlọ́gbọ́n.

Òwe 10

Òwe 10:9-22