Òwe 1:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ẹ bá ti gbọ́ ìbáwí ì mi ni,Ǹ bá ti tú ohun tí ó wà nínú ọkàn mi jáde fún yínkí n sì fi inú un mi hàn sí i yín.

Òwe 1

Òwe 1:20-32