Orin Sólómónì 8:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọwọ́ òsì rẹ ìbá wà ní abẹ́ orí mi,ọwọ́ ọ̀tún rẹ ìbá sì gbá mí mọ́ra.

Orin Sólómónì 8

Orin Sólómónì 8:2-11