Orin Sólómónì 8:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ ìbá rí bí arákùnrin misí mi èyí tí ó mú ọmú ìyá mi dàgbà!Èmi ìbá rí ọ ní òde,èmi ìbá fi ẹnu kò ọ́ ní ẹnu,wọn kì bá fi mi ṣe ẹlẹ́yà.

Orin Sólómónì 8

Orin Sólómónì 8:1-11