Àti ìfẹnukonu rẹ rí bí ọtí wáìnì tí ó dára jùlọ.Tí ó kúnná tí ó sì dùn,tí ń mú kí ètè àwọn tí ó sùn kí ó sọ̀rọ̀