Orin Sólómónì 7:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jẹ́ kí a lọ sínú ọgbà àjàrà ní kùtùkùtùláti wo bí àjàrà rúwébí ìtànná àjàrà bá là.Àti bí póméegíránéètì bá ti rúdí,níbẹ̀ ni èmi yóò ti fi ìfẹ́ mi fún ọ.

Orin Sólómónì 7

Orin Sólómónì 7:9-13