Orin Sólómónì 7:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Báwo ni ẹṣẹ̀ rẹ ti ní ẹwà tó nínú bàtà,Ìwọ ọmọbìnrin ọba!Oríkèé itan rẹ rí bí ohun ọ̀ṣọ́iṣẹ́ ọlọ́gbọ́n oníṣọ̀nà

Orin Sólómónì 7

Orin Sólómónì 7:1-7