Orin Sólómónì 6:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yí ojú rẹ kúrò lára mi;nítorí ojú rẹ borí mi.Irun rẹ rí bí i ọ̀wọ́ ewúrẹ́tí ó sọ̀kalẹ̀ wá láti Gílíádì.

Orin Sólómónì 6

Orin Sólómónì 6:1-7