Orin Sólómónì 6:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olùfẹ́ mi ti ṣọ̀kalẹ̀ lọ sínú ọgbà rẹ̀,sí ibi ibùsùn tùràrí,láti máa jẹ nínú ọgbàláti kó ìtànná lílì jọ.

Orin Sólómónì 6

Orin Sólómónì 6:1-10