Orin Sólómónì 5:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi sí ilẹ̀kùn fún olùfẹ́ mi,ṣùgbọ́n olùfẹ́ mi ti kúrò, ó ti lọọkàn mi gbọgbẹ́ fún lílọ rẹ̀.Mo wá a kiri ṣùgbọ́n, n kò rí i.Mo pè é ṣùgbọ́n, kò dáhùn

Orin Sólómónì 5

Orin Sólómónì 5:1-16