Orin Sólómónì 5:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo ti sùn ṣùgbọ́n ọkàn mi jí.Gbọ́! Olùfẹ́ mi ń kan ilẹ̀kùn.“Ṣí i fún mi, arábìnrin mi, olùfẹ́ mi,àdàbà mi, aláìlábàwọ́n miOrí mi kún fún omi ìrì,irun mi kún fún òtútù òru.”

Orin Sólómónì 5

Orin Sólómónì 5:1-5