Orin Sólómónì 5:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹṣẹ̀ rẹ̀ rí bi i òpó mábùtí a gbé ka ihò ìtẹ̀bọ̀ wúrà dáradáraÌrísí rẹ̀ rí bí igi kédárì Lẹ́bánónì,tí dídára rẹ̀ kò ní ẹgbẹ́.

Orin Sólómónì 5

Orin Sólómónì 5:12-16