Orin Sólómónì 4:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ètè rẹ dàbí òwú òdòdó;Ẹnu rẹ̀ dùn.Èrẹ̀kẹ́ rẹ dàbí ẹ̀là pàmógíránéètìlábẹ́ ìbòjú rẹ

Orin Sólómónì 4

Orin Sólómónì 4:1-7