Orin Sólómónì 4:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nádì àti Ṣáfírónì,kálámúsì àti kínámónì,àti gbogbo igi olóòórùn dídùn,òjíá àti álóépẹ̀lú irú wọn.

Orin Sólómónì 4

Orin Sólómónì 4:9-16