Orin Sólómónì 4:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Arábìnrin mi ni ọgbà tí a sọ, arábinrin mi, ìyàwó miìṣun tí a sé mọ́, oríṣun tí a fi èdìdì dì.

Orin Sólómónì 4

Orin Sólómónì 4:3-15