Orin Sólómónì 3:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ jáde wá, ẹyin ọmọbìnrin Ṣíónì,kí ẹ sì wo ọba Sólómónì tí ó dé adé,Adé tí ìyá rẹ̀ fi dé eNí ọjọ́ ìgbéyàwó rẹ̀,Ní ọjọ́ ayọ̀ ọkàn rẹ̀.

Orin Sólómónì 3

Orin Sólómónì 3:4-11