Orin Sólómónì 2:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Igi ọ̀pọ̀tọ́ mú èso tuntun jádeÀwọn àjàrà nípa ìtànná wọn fún ni ní òórùn dídùnDìde, wá, Olùfẹ́ mi;Arẹwà mi nìkan ṣoṣo, wá pẹ̀lú mi.”

Orin Sólómónì 2

Orin Sólómónì 2:11-17