Orin Sólómónì 1:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣọ fún mi ìwọ ẹni tí ọkàn mí fẹ́,Níbo ni ìwọ ń da agbo ẹran lọ.Níbi tí ìwọ mú agbo ẹran rẹ sinmi ní ọ̀sán.Kí ni ìdí tí èmi yóò fi jẹ́ obìnrin aṣánNí ẹ̀bá agbo ẹran àwọn ọ̀rẹ́ rẹ.

Orin Sólómónì 1

Orin Sólómónì 1:1-16