Oníwàásù 9:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọgbọ́n dára ju ohun—èlò ogun lọ,ṣùgbọ́n ẹlẹ́ṣẹ̀ kan a máa ba ohun dídára púpọ̀ jẹ́.

Oníwàásù 9

Oníwàásù 9:8-18