Oníwàásù 7:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó dára láti gba ìbáwí ọlọ́gbọ́n,ju fífetísílẹ̀ sí orin òmùgọ̀ lọ.

Oníwàásù 7

Oníwàásù 7:1-8