Oníwàásù 7:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ ma ṣe búburú jùlọ kí ìwọ má sì ṣe aṣiwèrèÈéṣe tí ìwọ yóò fi kú kí ọjọ́ rẹ tó pé

Oníwàásù 7

Oníwàásù 7:15-21