Oníwàásù 5:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Má ṣe yára pẹ̀lú ẹnu un rẹmá sọ ohunkóhun níwájú Ọlọ́runỌlọ́run ń bẹ ní ọ̀runÌwọ sì wà ní ayé,nítorí náà jẹ́ kí ọ̀rọ̀ rẹ mọ ní ìwọ̀n

Oníwàásù 5

Oníwàásù 5:1-4