Oníwàásù 3:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ohun tí ó wà ti wà tẹ́lẹ̀,ohun tí ó ń bọ̀ wá ti wà tẹ́lẹ̀,Ọlọ́run yóò sì mú kí àwọn ohun tí ó ti ṣẹlẹ̀ ṣẹ́yìn tún ṣẹlẹ̀

Oníwàásù 3

Oníwàásù 3:9-22