Oníwàásù 2:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi kò jẹ́ kí ojú mi ṣe aláìrí ohun tí ó bá ń fẹ́.N kò sì jẹ́ kí ọkàn mi ó ṣe aláìní ìgbádùn.Ọkàn mi yọ̀ nínú gbogbo iṣẹ́ mi,èyí sì ni èrè fún gbogbo wàhálà mi.

Oníwàásù 2

Oníwàásù 2:1-17