Oníwàásù 11:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí àwọ̀ṣánmọ̀ bá kún fún omi,ayé ni wọ́n ń rọ òjò síBí igi wó sí ì hà Gúṣù tàbí sí ìhà àríwáníbi tí ó wó sí náà, ni yóò dùbúlẹ̀ sí.

Oníwàásù 11

Oníwàásù 11:1-10