Oníwàásù 1:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo rò nínú ara mi, “Wòó, mo ti dàgbà, ọgbọ́n mi sì ti pọ̀ ju ti ẹnikẹ́ni tí ó ti ṣe alákòóṣo Jérúsálẹ́mù síwájú mi lọ, mo ti ní ìrírí púpọ̀ nípa ọgbọ́n àti ìmọ̀.”

Oníwàásù 1

Oníwàásù 1:10-18