Oníwàásù 1:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ǹjẹ́ ohun kan wà tí ẹnìkan le è ṣọ wí pé,“Wòó! Ohun tuntun ni èyí”?Ó ti wà tẹ́lẹ̀ rí ní ọjọ́ tó ti pẹ́Ó ti wà ṣáájú tiwa.

Oníwàásù 1

Oníwàásù 1:3-12