Onídájọ́ 9:52 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ábímélékì lọ sí ìṣàlẹ̀ ilé ìṣọ́ náà, ó sì ń bá a jà. Ṣùgbọ́n bí ó ti súnmọ́ ẹnu ọ̀nà ilé ìṣọ́ náà láti dáná sun ún,

Onídájọ́ 9

Onídájọ́ 9:45-53