Onídájọ́ 9:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n fún un ní àádọ́rin ṣékélì fàdákà láti ilé òrìṣà Bááli-Béritì, Ábímélékì fi owó náà gba àwọn jàǹdùkú àti aláìníláárí ènìyàn tí wọ́n sì di olùtẹ̀lé rẹ̀.

Onídájọ́ 9

Onídájọ́ 9:1-8