Onídájọ́ 8:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gídíónì àti àwọn ọ̀ọ́dúnrún (300) ọkùnrin tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀ tẹ̀ṣíwájú láti lépa àwọn ọ̀ta bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ó ti rẹ̀ wọ́n, wọ́n dé Jọ́dánì wọ́n sì kọjá sí òdì kejì.

Onídájọ́ 8

Onídájọ́ 8:1-6