Onídájọ́ 8:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àlè rẹ̀, tó ń gbé ní Ṣékémù, pàápàá bí ọmọkùnrin kan fún un tí ó pe orúkọ rẹ̀ ní Ábímélékì.

Onídájọ́ 8

Onídájọ́ 8:29-32