Onídájọ́ 7:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sọ fún wọn pé, “Ẹ máa wò mí, kí ẹ sì máa ṣe ohun tí mo bá ṣe. Nígbà tí mo bá dé igun ibùdó wọn ẹ ṣe ohun tí mo bá ṣe.

Onídájọ́ 7

Onídájọ́ 7:15-25